See List Of Yoruba Praise And Worship Songs – 1

21. Olorun to da awon oke igbani – Lyrics
Olorun toda awon oke igbani
Eyin ni mo fi ope mifun 2ce

Tani un o tun gbega o
bi ko se Baba loke
Tani un o tun fi ope e fun

Olorun to da awon oke igbani
Eyin ni mo fi ope e mi fun

22. Emi o ri o ri ooo – Lyrics
Emi o ri o ri ooo, Olorun mi sugbon mo feel re,
Emi o ri o ri ooo, Olorun mi sugbon mo feel re,
I have a feeling, Olorun mi wipe e wa laaye ooo,
I have a feeling Olorun mi wipe e wa

Recommended: List Of All Nigerian Praise And Worship Songs

23. Kabiye O si – Lyrics
Kabiye O si ooo
You are the GOD of Heaven and Earth
Kabiye O si ooo
Kabiye O si.

24. Oruko re ti niyin to – Lyrics
Oba to seun teni kan kole se
Oruko re ti niyin to (x2)……
Oluwa!
Oluwa, Oluwa, Oruko re ti niyin to
Ni gbogbo aiye
Oruko re ti niyin to…………(x4)

See Also: List Of Hausa Praise And Worship Songs

25. Oluwadara – Lyrics
Oluwadara, Oluwadara, Oluwadara
O! Dara
Oluwadara, O! Dara (x2)
Oluwatoyin, Oluwatoyin, Oluwatoyin
O! Toyin
Oluwatoyin, O! Toyin (x2)
Oluwatosin, Oluwatosin, Oluwatosin
O! Tosin
Oluwatosin, O! Tosin (x2)
Oluwafemi, Oluwafemi, Oluwafemi
O! Femi
Oluwafemi, O! Femi (x2).

26. Tori na le se n je JEHOVAH – Lyrics
Tori na le se n je JEHOVAH 2x
Eleshe Elewi, Elewi Eleshe
Tori na le se n je JEHOVAH

You May Also Like: List Of Efik Praise And Worship Songs

27. Iwo ni moni laye lorun – Lyrics
Iwo ni moni laye lorun(2ce)
Jesu iwo ni moni ni baba(2ce)

28. Eyin ni baba – Lyrics
Eyin ni baba to to baba
Eyin ni baba to ju baba lo

29. Osuba re re o – Lyrics
Osuba re re o
Osuba re re o
Oba ta o ri, ta a ri se owore, Osuba re re o

30. Alagbara l’olorun mi – Lyrics
Alagbara l’olorun mi
Alagbara ni Jesu mi o
T’oba ti soro be na l’nri
Alagbara l’olorun mi

31. Eyin le to o baba – Lyrics
Eyin le to bi
Eyin le to oooo
Eyin le to lati gba ogo
Eyin le to o baba

See List Of All Igbo Praise And Worship Songs

32. Orun..oun aiye – Lyrics
Orun..oun aiye..kunfun ogo re…orun..oun aiye kunfun ogo ire…egbegberun..awon irawo..ke de ogo ire..kini owa se mi…ti wun onile…majuba re o e..

33. Alagbara lo olurun mi Agbara agbara agbara yi po o Agbara….. – Lyrics

34. Olorun baba modupe – Lyrics
Koletoyen o ore
Koletoyen o
Toba tiya unope o o
Kowa bami jo o
Kowa bami yo
Ore to baba se laye mi
Pareke
Olorun baba modupe-2x
Bi aba seni lore
Ope la’adu
Olorun baba modupe o
Laso,faso, so so so so
Do re mi la so

35. Ayo ni temi – Lyrics
Motilayo ninu Jesu ALelluyah
Oba mimo to fife ra mi pada
Titi aye lemi o ma k’alelluya
Aleluyah f’Oba mi Olore

Call: Mo rayo, eh eh ayo
Response: Ayo ni temi
All: Oh oh ayo, oh oh ayo ni temi

15 COMMENTS

  1. They are all lovely & inspirational songs which really help me a lot about the meaning and pronunciation of some of the Yoruba songs. Thanks a lot.

Leave a Reply