1. OLUWA MI MO WA DUPE – Lyrics
OLORUN mi mo wa dupe
OLUWA mi mo wa dupe
EYIN L’oba to se t’ana
Eyin L’oba to se t’oni
O daju pe E o se t’ola
OLORUN mi mo wa dupe

2. Kabiesi, Oba gbogbo aye – Lyrics
Kabiyesi, Oba gbogbo aye
Kabiesi, Oba gbogbo aye
Baba Ese gan an

3. Alagbara bi ara o, Eya Judah – Lyrics
Alagbara bi ara o, eya Judah
Kiniun de, Eya Judah
Oba Alade Wura de
O de, O de,
Oba Alade wura de

Recommended: List Of All Nigerian Praise And Worship Songs

4. Kilo mu t’omiwa? – Lyrics
kilo mu tomiwa?
ohun rere lo mu tomiwa
o le iku w’ogbo
O le aarun w’ole
O wa so’banuje mi dayo
Ohun rere lO’mu tomiwa
Abi beeko o?
Aaah, Bee naa ni
Aye mi dara o
Aah, Bee naa ni

5. Ti Mba Sop’Olorun O See To – Lyrics
Ti mba sop’Olorun o see to
Ti mba sop’Olorun o see to
Ti mba sop’Olorun o see to o
Abaramooreje ni mi o eeh

6. Olore ofe, Eleruniyin – Lyrics
Olorun otito
Mo gbe o ga

See Also: List Of Hausa Praise And Worship Songs

7. Jesu Oloore o… Oloore – Lyrics
Messiah Oloore o… Oloore
Jesu Oloore o… Oloore
Messiah Oloore o… Oloore
O ku nitori mi…. Oloore
O jiya nitori mi o… Oloore
E wa bami gboroyin yi, Iroyin ayo, Iroyin rere
E wa bami gboroyin yi, Iroyin ayo, Iroyin rere
Iroyin toju’royin lo… Iroyin ayo, Iroyin rere

8. Alayo ni mi – Lyrics
Emi yoo mayo
Jesu layo mi
Ewa bamiyo

9. Alaaye ni o maa yin O o Baba – Lyrics
Alaaye ni o maa yin O o Omo
Eni to ti ku kolee yin O
Alaaye ni o maa yin O o Baba
Eni to ti ku kolee yin O
Alaaye ni o maa yin O o Baba

10. Kabiyesi Re Iwo lOba – Lyrics
Kabiyesi Re Iwo lOba
Ko mama s’Oba bi Ire
Kabiyesi Re Iwo lOba

11. Alaayo ni – Lyrics mi – Lyrics
Emi yoo maa yo
Jesu layo mi
Ewa bamiyo

You May Also Like: List Of Efik Praise And Worship Songs

12. Nigba ti mo ro – Lyrics
Tife Re laye mi Jesu
Nigba ti mo ro
T’aanu Re O jo mi loju

13. Fehinti fehinti – Lyrics
Jesu ni mo fehinti
Jesu ni mo fehinti
mi o le subu
Rara rara, mi o le subu
Rara rara, mi o le subu
Fehinti fehinti
Jesu ni mo fehinti
Jesu ni mo fehinti
mi o le subu

14. Olorun Agbaye o You are Mighty (2x) – Lyrics
Seb’iwo lo f’oju orun s’aso bora (2x)
Olorun AGBAIYE o You are Mighty o

15. Ope ye o jesu no – Lyrics
ope ye o jesu no, apata igbala, olorun iyanu imo alade alafia ope ye o jesu mi

16. Ose mi L’aanu!
– Lyrics
Ose mi L’aanu!
Ma polongo re
Oba to se mi laanu
Aaaah aaaah
Emi a polongo re.

17. Alagbara lo olurun mi
– Lyrics
Alagbara lo olurun mi
Agbara agbara agbara yi po o
Agbara…..

18. OLORUN mi – Lyrics
Olorun mi/2x
iwo loju ti mo fin riran
iwo ni kokoro ti mo fin shilekun
iwo lorin ti mo un ko
ina aye e ko je ko jo mi
kini mo ni ti mo le fun o o?
Mo wo le mo wa juba re.
OLORUN mi

See List Of All Igbo Praise And Worship Songs

19. Orun oun aye – Lyrics
Orun oun aye, kun fun ogo re
Orun oun aye kun fun ogo re
Egbegberun awon irawo kede ogo re
Kini o was she mi, ti n o nile ma juba re o e.

20. Ta lo dabi Ire – Lyrics
Ta lo dabi Ire, Jesu
ta lo da bi ire ooo, Alagbara
Oba to gbe ogo kari ogo oooo
lati inu ogo, lo sinu ogo, oba ti ki su, Oba ti ki re, talo dabi ire
ooo, Alagbara

See List Of Yoruba Praise And Worship Songs – 2

12 COMMENTS

Leave a Reply